paroles de chanson / Apostle Daniel Ekunola parole / Ojo Agbara Na lyrics  | ENin English

Paroles de Ojo Agbara Na

Interprète Apostle Daniel Ekunola

Paroles de la chanson Ojo Agbara Na par Apostle Daniel Ekunola lyrics officiel

Ojo Agbara Na est une chanson en Anglais

OJO AGBARA NA

All: Ojo agbara na ti osan doru
T’aso ‘jo mimo kale
Irawo meje loyo ni oke orun
Awon eye iwo nke luli
Awon eye iwo nke luli
Luli ore-ofe
Irawo meje loyo ni oke orun
Awon eye iwo nke luli

L/v: Osu kesan ojo Kankandinlogbon
Ni odun 1947, ni eyi sele

All: Ni eyi sele, lagogo meta osan
Gbowo SBJ Oshoffa
Eyi loko ikehin
To sokale latorun
Iye, iye, iye lohun na nke
Ijo Mimo Celestial

Int: Mo mbe ninu ododo

All: Ise lohun na ke emura sise
Sise pelu ‘fe mimo
Ere ise re ni iwo yio gba o
Sise pelu’fe mimo
Ejeka mura sise
Sise pelu ife mimo
Ere ise re ni iwo yio gba o
Sise pelu ‘fe mimo

All: Ero ara ota loje s’Olorun
Idunnu Olorun l’emi
Iye awa to gba jesu l’oluwa
Eje ka sin ninu ife
Eje ka sin ninu ife
Eje ka sowopo
Iye awa to gba jesu l’oluwa
Eje ka sin ninu ife

All: Ife lohun na ke
Eje kalo ‘fe
Bi iwe mimi tiwi
Korinti kinni, Ori ketala
Ife lohun na nko wa
Bere la tese kinni,
Titi de ipari re
Korinti kinni, ori ketala
Ife lohun na nko wa

All: Igbagbo ni idaniloju
Ohun ti a nre ti
Ijeri ohun ti a kori
Oniyemeji ki yio ri ohunkohun gba
Jesu Kristi to fun wa
Eni to bani Jesu
Ohun lohun bori aye
Oniyemeji ki yio ri ohun kohun gba
Jesu Kristi to fun wa

All: Eje ka toro agbara isin dopin
Ibere ko loni se
Lawa le r’ode iye ti ati pese
Sile fun ijo mimo
Ibere ko lonise
Bi kode aisedopin
Eje ka sise ka le gba de ogo
Ta pese fun ijo Mimo

L/v: Ijo mimo, latode Orun
Baba wa Orun , lofi ranse o
B’aye fe, baraye ko,
Yio bori dandan
B’ota fe bi satani ko
Ife Oluwa ni lati se

All: Bi gbogbo aye, dite mowa
Won gbodo teri ba fun Oluwa
Eyin omo Ijo mimo
Edide keyin Oluwa
Halleluyah ni orin wa
Halleluyah wa ninu ise wa
Bi aye fe, bi aye ko 2x
Won ateriba fun Oluwa

L/v: Awa n’jo mimo, Aladura

All: Ijo mimo dara
Jesu baba wa f’ohun
Rere sile
Inu wa si dun, Halleluyah

All: Awa nyo ninu Jesu
Jesu mbe lehin wa
Ohun gbogbo ti a
Mbere lowo re
Osi ti fi fun wa, Haleuyah

All: Awa nijo mimo
Ijo mimo mbe
Awon angeli yo
Pelu wa
Ara was i ti ya, Halleluyah.

All: Apalase lagbala orun
Pe’ ki’jo yi ma bisi
Apalase lagbala orun
‘pe kosi maa re si
Titi gbogbo iponju aye 2x
Yio fi tan laye
Titi jesu olugbala
Yio fi pada wa

Interlude:

All: Omo njo, Omo nyo
Nigbati, baba wa nyo
Pelu orin ayo
Halleluyah la o ma ko
Nigbati maleka nyo 2x
Pelu orin ayo
Mimo mimo lao mako
Nigbati oba ogo
Sewa logo

Intro: iwo kuku n’mole wa
Emimimo e seo

All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku n’mole wa
Ninu ijo mimo

All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku n’segun
Ninu ijo mimo

All: Emimimo Ade o
Emi awon woli
iwo kuku lagbara ra wa
Ninu ijo mimo

L/v: Baye bawa gbogun de

All: awa la o bori won

All: awa la o leke won
Fona abayo han wa o, baba awa.

L/v: Iwo kuku lagbara wa
Emimimo a de o

All: Emimimo ade o
Emi awon woli etc. 3x

L/v: Wo o le All: Adaba mimo
L/v: Wo o le All: Adaba Ogo
L/v: Adaba All: Adaba towa lehin ogba
Adaba ologo
Adaba mimo o, Wo o le

L/v: Iwo kuku nimole wa
Emimimo atide

All: Emimimo Ade
Emi awon woli .etc/ 3x

L/v: Iwo kuku latona we ninu ijo mimo
Iwo ko nsowa lo ndabobo wa loojo jumo
Iwo kuku lafi nriran ninu ijo Celestial Church
Emimimo Sokale wa, bawa ton ijo mimo se to
Holy spirit sokale wa, was a ko so ijo mimo

L/v: Gbogbo Agbara /2x Jesu lowo Re lowa
Kosi lowo oso o, koma si lowo aje o rara

All: Gbogbo agbara, gbogbo agbara
Jesu lowo Re lowa

L/v: Iwo kuku nimole wa ninu ijo mimo o

All: Emimo ade o, Emi awon woli. Etc.
Droits parole : paroles officielles sous licence Lyricfind respectant le droit d'auteur.
Reproduction des paroles interdite sans autorisation.

Commentaires sur les paroles de Ojo Agbara Na

Nom/Pseudo
Commentaire
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - Tous droits réservés. www.paroles-musique.com
Connexion membre

Se connecter ou créer un compte...

Mot de passe oublié ?
OU
CREER COMPTE
Sélectionnez dans l'ordre suivant :
1| symbole à droite de l'étoile
2| symbole en haut de l'oeil
3| symbole à gauche de la cible
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid