song lyrics / Traditional / Jesu Oluf' okan Mi lyrics  | FRen Français

Jesu Oluf' okan Mi lyrics

Performer Traditional

Jesu Oluf' okan Mi song lyrics by Traditional official

Jesu Oluf' okan Mi is a song in Yoruba

1. JESU oluf’ okan mi,
Je ki nsala s’ aiya Re;
Sa t’ irumi sunmo mi,
Sa ti iji fe s’ oke;
Pa mi mo, Olugbala,
Tit’ iji aiye y’o pin,
To mi lo s’ ebute Re,
Nikehin gb’ okan mi la.

2. Abo mi, emi ko ni,
Iwo l’ okan mi ro mo;
Ma f’ emi nikan sile,
Gba mi, si tu mi ninu.
Iwo ni mo gbekele,
Iwo n’iranlowo mi,
Ma sai f’iye apa Re
D’abo b’ori aibo mi.

3. Krist’,’wo nikan ni mo fe,
N’nu Re, mo r’ohun gbogbo;
Gb’emi t’o subu dide,
W’alaisan, to afoju;
Ododo l’oruko Re,
Alaisododo l’emi,
Mo kun fun ese pupo,
Iwo kun fun ododo.

4. ‘Wo l’opo ore-ofe
Lati fib o ese mi:
Je ki omi iwosan
We inu okan mi mo;
Iwo l’orisun iye,
Je ki mbu n’nu Re l’ofe,
Ru jade n’nu okan mi,
Si iye ainipekun.
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.

Comments for Jesu Oluf' okan Mi lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol to the left of the trash
2| symbol to the right of the envelope
3| symbol at the bottom of the cloud
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid