song lyrics / Dami lola drizzy / Ifa Wa Kayejo lyrics  | FRen Français

Ifa Wa Kayejo lyrics

Performer Dami lola drizzy

Ifa Wa Kayejo song lyrics by Dami lola drizzy official

Ifa Wa Kayejo is a song in Yoruba

Ifc WcKcYEJO
Mo tun ti de
Ge ge bi mo se de
Mo ti be olodumare
Ki baba ba mi se
Mo lo irin ajo
cwon ota won Fe kin de
Shugbon ifa olokun
Baba ti bami se

Mo mo pe orin ti mo Fe ko yii
Won ma gbe ogun
Shugbon eni logo
Ko le se alai logun
Eni lo lasan
Won mu Okuta
Won tun so fun
Mo mo pe
Ifa a bami segun

Bi Erin ba ji
Erin aki olu igbo o
Bi Efan ba ji
Efan aki olu odan
Erin to ba ji
Ti ko ba ki olu igbo o
Beeni efan to ba ji
Ti ko ba ki olu odan

cwon mejeji
cfi owo arawon fi ka asa
Mi o ba Tija wa
Beeni mi o ba tere wa
To ba ni isoro
cwa naa lo ma saba
cwon to fi Oruko imi gba yin le gan
Won ni ifa

Ifa ti gbaye lo
Ogberi o mo
Bi iro ba lo fun Ogun odun
Oto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
Ema je ka tako arawa
Pelu oro siso o

Ifa ti gbaye lo
Ogberi o mo
Bi iro ba lo fun Ogun odun
Oto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
Ema je ka tako arawa
Pelu oro siso o

Ebe ni mo be
cpari inu mi
Ko ma se je kin ri ogun
Elenini
Ki awon kan
Koma se sepin mi
Ki awon Omo araye
Koma se damu mi

Ire ni kin ma ri
Baba ma je ri ibi
Oju to ma ri ire
Kole se alai ri ibi
Ti won ban wa mi fun aburu
Baba ma je ko ri mi
Baba go cdura mi o
Ki oto su mi

Ope fun olorun
Oba to to
Iyin ye oo
Odumare
Ogo ye oo
Orunmila aa
Iyin ye o oo
csiwaju rere

Ifa ti gbaye lo
Ogberi o mo
Bi iro ba lo fun Ogun odun
Oto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
Ema je ka tako arawa
Pelu oro siso o
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.

Comments for Ifa Wa Kayejo lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol to the left of the cross
2| symbol to the right of the eye
3| symbol at the bottom of the trash
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid