song lyrics / Tinuade / Oluwa Iyanu lyrics  | FRen Français

Oluwa Iyanu lyrics

Performer Tinuade

Oluwa Iyanu song lyrics by Tinuade official

Oluwa Iyanu is a song in English

OLUWA IYANU LYRICS

Chorus: (lead) 1x
Oluwa iyanu ni (3x) o
Ko s'oba bi ire

All repeat chorus 2x

verse 1:
Oba orun
Alagbara julo
Aterere ka ye o
Oba to n gbani
Eleje p'ese re
o gba mi lowo ese o
o so mi d'omo Jesu mo dupe o

All Repeat chorus (2x)

verse 2:
O f'ayemi se'yanu
O fi'se mi se'yanu
ohun gbogbo ti mo je o
iyanu ni
Mo wa dupe e se o
F'ore igba gbogbo
Alagbada Ina
iyanu l'oruko re

Repeat chorus 2x

interlude----

Chant (lead):
Olorun iyanu dansaki re
Oba a mu ni ko ja ninu Ina
Alagbara to j'alagbara lo
ipa to bori ipa
Aragba yamu yamu
Eleti gb'aroye

Eh eh eh ah
ko s'oba bi ire

call: Jesu (5X) o

Resp: ko s'oba bi ire

call:Aduro ti ni lojo ogun le o
Resp: ko s'oba bi ire

call: O gbe ni ni'ja k'eru o b'onija o
Resp: ko s'oba bi ire

call: A ti ni leyin ko ju ma ti ni
Resp: Ko s'oba bi ire

lead:
Eh ko s'oba bi ire o oba nla
Ko s'oba bi ire
oni majeemu mi o
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.
Writer: TINUADE ILESANMI
Copyright: ONErpm

Comments for Oluwa Iyanu lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol at the bottom of the smiley
2| symbol to the left of the helmet
3| symbol to the left of the trash
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid