paroles de chanson / Grace Ojo parole / Iwo Ni lyrics  | ENin English

Paroles de Iwo Ni

Interprète Grace Ojo

Paroles de la chanson Iwo Ni par Grace Ojo lyrics officiel

Iwo Ni est une chanson en Anglais

Iwo ni Jesus mi Iwo ni
Bi ko ba n sola Re Jesu talo mo mi o
Iwo ni, Ola Re ni mo n je

Iwo ni Jesus mi Iwo ni
Iwo ni mori nigba ti mo kepe O
Iwo lo n je mi nigba kugba Baba
Iwo ni, Ola Re ni mo n je

Iwo ni Jesus mi Iwo ni
Bi ko ba n sola Re Jesu talo mo mi o
Iwo ni, Ola Re ni mo n je

Erupe lasan lasan ni mi kini mo jamo
Emi Re Emi mimo Olorun lo gbe mi ro
Oun lo se mi logo to somi deni an ponle
A Iwo ni ola Re ni mon je

Eni ti oni Jesu aiye Re koni itumo rara
Eje odo aguntan lo kawa ye fun idalare
Ose o Jesu Olurapada gba gbogbo ogo
Iwo ni O sewa logo o Oseun

Iwo ni Jesus mi Iwo ni
Bi ko ba n sola Re Jesu talo mo mi o
Iwo ni, Ola Re ni mo n je

Otosi else sa ni gbogbo wa Koko je
Owu O ninu ola nla Re lol sowa domo
Omu mi jade kuro lati inu ira wa
Omu mi joko larin awon Oba alade

Gba tesu somi mole sinu oko eru
Koseni totobe lati se itusile funmi
Owo Re ni mori o to mumi jade Logan
Logan ti ode o ni itusile wonu aiye mi

Iwo ni Jesus mi Iwo ni
Bi ko ba n sola Re Jesu talo mo mi o
Iwo ni, Ola Re ni mo n je

Ola Jesu ni mo n je laiye mi

Jesu mi Iwo ni

Iwo ni mo n ri lowuro, losan, loru

Jesu mi Iwo ni

Iwo ni mo n kepe to n jemi Logan Logan

Jesu mi Iwo ni

Koseni ti mo mo tole seru eyi funmi

Jesu mi Iwo ni

Afi Iwo nikan loye fun ola, iyin atogo

Jesu mi Iwo ni

Ah bi ko ban sola Re Jesu laiye mi

Jesu mi Iwo ni

Talo momi o talo mo Iran mi

Jesu mi Iwo ni

Iwo ni momo Iwo ni mori nigba gbogbo

Jesu mi Iwo ni

Iwo lole seru doba alade

Jesu mi Iwo ni

Iwo ni mori o Jesu Iwo nikan momo

Jesu mi Iwo ni

Iwo lode mi lade eye o

Jesu mi Iwo ni

Gbati ko soluranlowo Iwo lo yoju Simi

Jesu mi Iwo ni

Iwo lolugbala, Iwo loluwosan okan mi

Jesu mi Iwo ni
Droits parole : paroles officielles sous licence Lyricfind respectant le droit d'auteur.
Reproduction des paroles interdite sans autorisation.

Commentaires sur les paroles de Iwo Ni

Nom/Pseudo
Commentaire
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - Tous droits réservés. www.paroles-musique.com
Connexion membre

Se connecter ou créer un compte...

Mot de passe oublié ?
OU
CREER COMPTE
Sélectionnez dans l'ordre suivant :
1| symbole à droite de l'enveloppe
2| symbole à gauche du cadenas
3| symbole en bas du coeur
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid