paroles de chanson / Db Comic parole / Oluwa Ari'se Yin lyrics  | ENin English

Paroles de Oluwa Ari'se Yin

Interprètes Db ComicBbO

Paroles de la chanson Oluwa Ari'se Yin par Db Comic lyrics officiel

Oluwa Ari'se Yin est une chanson en Yoruba

Oluwa a maa rise yin o,
Oluwa a maa rowo yin o,
Awon tooti gan wa tun wa n,
Fola a wa toro,
Gbogbo awon tati ranlowo ton,
Sebi olorun kowa tan bi,

Awon toti gan wa,
Tun wa n fola a waa toro,

Mooooooduupeee mio mubo,
Mi o mubo,
Mi o mubo ooooooooooooooooo,
Nitori amubo lota n pinnu,
Fun mi,
Se ni won n reti biii,
Ki n wo,
Ki n subu ninu,
Irinajo yii ooo Okomi,
Kooto ta won people yin dee ,
Sile mi o Kosi Oba mi,
Wo bi,
Tofaanu mu mi de eeeeeeeeeeee,
Ba wo la a se deebi yii naa oo OKOMI,
Awon to je oloola ton fola,
Jeyan,
Won tun jowu ohun ti mo ni,
Korumi lojuuuuuuuu,
Mo meni to saanu mi,
Olorun awon baba wa,
A se wipe Oloofo eyan le pada di ologo eyan,
Igbedide ti Mo ni owo re ni,
Ola ti Mo ni owo re ni,
Ogo to buyo Lara mi,
Tawon eyan yii n fii n pemi Lologo owo re ni,
Owo re ni,
Owo re ni aaaa,
O sanu de ni wipe,
Awon toti gan tun wa n fola Emi n toro,
Mogaji awon alaagbara,
Iwo lobami seeeeeeeee,
Awon toti fiigba kan pe mi loloofo eyan ri,
Won fola Emi tooro,
Alaatilehin mi iwo lomumi debi oooogo ogo Fun oruko yin,
Awon to ti gan aaaaa,
Won n fola a wa toro,
Nkan o le taye awa eyan yii,
Jade,
Awon to ti fi gba kan,
Se shi o si wa oooo,
Won fola a wa toro,
Okomi,
Baba mi iwo loran wa lowo,
Debitaade yiii ooo,

Oluwa a maa rise yin o,
Oluwa a maa rowo yin o,
Awon tooti gan wa tun wa foola awa timooro,

O ma maa se Eledumare,
Mo maa maa dupe dupe,
Alatilehin,
A ni bi kii ba se fe re oo,
Kinni Iba maa wo,
Nitori wipe,
Awon toti gan wa tun wa n fola
Awa toro,

Awon to ti gan waoo,
Awon tooti gan mi n fola Emi toro,
Awon to ti romipin o,
Awon toti ro mi pin won wa fola a mi tooro.
Droits parole : paroles officielles sous licence Lyricfind respectant le droit d'auteur.
Reproduction des paroles interdite sans autorisation.

Commentaires sur les paroles de Oluwa Ari'se Yin

Nom/Pseudo
Commentaire
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - Tous droits réservés. www.paroles-musique.com
Connexion membre

Se connecter ou créer un compte...

Mot de passe oublié ?
OU
CREER COMPTE
Sélectionnez dans l'ordre suivant :
1| symbole à droite de la poubelle
2| symbole en haut du téléviseur
3| symbole à droite de la calculatrice
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid