paroles de chanson / Dami lola drizzy parole / Isese (Lagba) lyrics  | ENin English

Paroles de Isese (Lagba)

Interprète Dami lola drizzy

Paroles de la chanson Isese (Lagba) par Dami lola drizzy lyrics officiel

Isese (Lagba) est une chanson en Yoruba

Isese lagba

Ifa be
Bi ti atijo
cwa ni co sin baba
Bi ti atijo
Ifa o je fi wa le fun awon ota pa
Ti won ba lo be si wa
Won ma farapa

Eyin omo oduduwa
Eyin Omo orunmila
Eje ka fi ife para po
Ka fi gbe esin ga
Ninu gbogbo nkan
Ti aba se
Ema je ka fi ibi su olore
E je ka fi idunu ati ayo
Ka fi tun esin wa se

Ni Tori isese lagba
Isese lagba
(Ki ama se gba gbe ile)
Isese lagba
Isese lagba
(Mummy ma so fun mi pe)
Isese lagba
Isese lagba
(Ki ama se gba gbe ile)
Isese lagba
Isese lagba

Moni ifa be
Orunmila be
Esu be
Moni egbe be
Sango be
Oya be
Moni egungun be
cje be
Iyemoja be
Moni ewe be
Egbo be
Isese be

Ifa be
Bi ti atijo
cwa ni co sin baba
Bi ti atijo
Ifa o je fi wa le fun awon ota pa
Ti won ba lo be si wa
Won ma farapa

Eyin omo oduduwa
Eyin Omo orunmila
Eje ka fi ife para po
Ka fi gbe esin ga
Ninu gbogbo nkan
Ti aba se
Ema je ka fi ibi su olore
E je ka fi idunu ati ayo
Ka fi tun esin wa se

Ni Tori isese lagba
Isese lagba
(Ki ama se gba gbe ile)
Isese lagba
Isese lagba
(Mummy ma so fun mi pe)
Isese lagba
Isese lagba
(Ki ama se gba gbe ile)
Isese lagba
Isese lagba
Droits parole : paroles officielles sous licence Lyricfind respectant le droit d'auteur.
Reproduction des paroles interdite sans autorisation.

Commentaires sur les paroles de Isese (Lagba)

Nom/Pseudo
Commentaire
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - Tous droits réservés. www.paroles-musique.com
Connexion membre

Se connecter ou créer un compte...

Mot de passe oublié ?
OU
CREER COMPTE
Sélectionnez dans l'ordre suivant :
1| symbole à droite de la cible
2| symbole à gauche de la valise
3| symbole en bas de la maison
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid