paroles de chanson / Abidogun Modupe parole / Sekeseke lyrics  | ENin English

Paroles de Sekeseke

Interprète Abidogun Modupe

Paroles de la chanson Sekeseke par Abidogun Modupe lyrics officiel

Sekeseke est une chanson en Yoruba

Emi o korin yin Oluwa
Nitori o po ni Ogo
Emi o korin yin Oluwa
Nitori o po ni Ogo

In the greatness of thy excellency Iwo bi won wo awon to dide si o Baba
nitori owo otun re ni Ogo oo ati agbara nla

Owo otun re fowon tutu pharaoh ati awon Omo Ogun re

In the greatness of thy excellency iwo bi won wo, awon to dide si o Baba thou has overthrown them that rose up against thee Owo otun re fowon tutu
Ha Emi o korin Soluwa he has triumph gloriously by the breath of the nostril Omi wojo duro gangan Ha Ogun aye mi to n tele mi Baba bi Ogun naa wo
Ogun idile ni to n tele mi Baba bi Ogun naa wo

Baba bi Ogun naa wo bi Ogun naa wo
Baba bi Ogun naa wo bi Ogun naa wo

Ogun aye mi to n tele mi Baba bi Ogun naa wo
Airomo gbejo ni to n tele mi Baba bi Ogun naa wo
Ogun Jericho ni to n tele mi Baba bi Ogun naa wo

Baba bi Ogun naa wo bi Ogun naa wo

Ogun to nja Nigeria

Baba bi Ogun naa wo bi Ogun naa wo

Ogun aye mi to n tele miii Baba bi Ogun naa wo
Ogun Jabesi ni ninu ayemi Baba bi Ogun naa wo

Oja sekeseke mi
Jesu ja sekeseke mi oo oja sekeseke mi
Ide mi tija o Oja sekeseke mi Oja sekeseke mi
Moti dalayo Oja Sekeseke mi oja sekeseke mi

Oku ki n leriye Oja sekeseke mi o
Ofemi re sile fun wa kawa leriye
Ide mi tija o Oja sekeseke mi Oja sekeseke mi
Moti dalayo Oja Sekeseke mi oja sekeseke mi

Ha Idemi jaaaa gba
Jesu tija sekeseke mi o
Oti ja sekeseke aisan Oja sekeseke ide
Jesu ja sekeseke mi
Oku fun wa kaleriye o kawa le joba ni keyin e
Owa ja sekeseke wa awa ti bo lowo iku
Jesu tija o Oja Sekeseke mi oja sekeseke mi

Oja sekeseke aisan Oja sekeseke mi Oja sekeseke mi
Oma ja sekeseke o Oja sekeseke mi Oja sekeseke mi
Jesu tija o
Oti ja o Oja sekeseke mi Oja sekeseke mi
Droits parole : paroles officielles sous licence Lyricfind respectant le droit d'auteur.
Reproduction des paroles interdite sans autorisation.

Commentaires sur les paroles de Sekeseke

Nom/Pseudo
Commentaire
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - Tous droits réservés. www.paroles-musique.com
Connexion membre

Se connecter ou créer un compte...

Mot de passe oublié ?
OU
CREER COMPTE
Sélectionnez dans l'ordre suivant :
1| symbole à gauche du smiley
2| symbole à gauche de la loupe
3| symbole en bas du pouce en l'air
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid