song lyrics / Tee Jewel / Ajé lyrics  | FRen Français

Ajé lyrics

Performers Tee JewelJoel Akintimehin

Ajé song lyrics by Tee Jewel official

Ajé is a song in Yoruba

Ye o ye o ye o

A o ni shubu ko ni rewa ajé
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
A o ni sukun nibi ta tin jaye o
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
Gbogbo lala Koko Janjan a wole Lówó Kan (Ajé)
Wa dagba Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)
Àní Gbogbo lala Koko Janjan a wọlé Lówó Kan (Ajé)
Wa dàgbà Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)

Owo a to WA na
Ojojumọ la ma ball
As you spend your money
Na so I go spend my money
Alanu o ni wón wa
A ma ra bugatti fún mama
Easy for you to japa
You enter Dubai go buy wrapper

Sebi ayé dada Ni (Sebi ayé dada Ni )
Timba pawo yen ni foreign (pawo yen ni foreign)
Sebi ayé dada Ni (Sebi ayé dada Ni )
Toluwa bá cover mi (oluwa bá cover mi)
Sebi ayé dada (Sebi ayé dada Ni )
O ma jayé kò sí worry (laye kò sí worry)
Sa sayé dada (sayé dada)

A o ni shubu ko ni rewa ajé
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
A o ni sukun nibi ta tin jaye o
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
Gbogbo lala Koko Janjan a wole Lówó Kan (Ajé)
Wa dagba Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)
Àní Gbogbo lala Koko Janjan a wọlé Lówó Kan (Ajé)
Wa dàgbà Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)

Mo bẹrẹ alubarika o
Jẹ ka rówó kà o
Lagbara Oluwa o
A o ni taraka nínú ilé wa o
Ko ja s'ọpe ko Dayọ
Ki wọn má pèmí lọmọ alayọ
Jẹ ka rí se se jẹ ka k'ore Oko de'le

Sebi ayé dada Ni (Sebi ayé dada Ni )
Timba pawo yen ni foreign (pawo yen ni foreign)
Sebi ayé dada Ni (Sebi ayé dada Ni )
Toluwa bá cover mi (oluwa bá cover mi)
Sebi ayé dada (Sebi ayé dada Ni )
O ma jayé kò sí worry (laye kò sí worry)
Sa sayé dada (sayé dada)

A o ni shubu ko ni rewa ajé
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
A o ni sukun nibi ta tin jaye o
(Ajé) Ajé (Ajé) oh no no (Ajé)
Gbogbo lala Koko Janjan a wole Lówó Kan (Ajé)
Wa dagba Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)
Àní Gbogbo lala Koko Janjan a wọlé Lówó Kan (Ajé)
Wa dàgbà Wa jola Ọmọ (Ajé)
Lágbára ọlọrun o (Ajé)
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.
Copyright: Sentric Music

Comments for Ajé lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol at the bottom of the cross
2| symbol at the bottom of the eye
3| symbol to the left of the television
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid