song lyrics / Segun Bright / Surulere lyrics  | FRen Français

Surulere lyrics

Performer Segun Bright

Surulere song lyrics by Segun Bright official

Surulere is a song in English

Suurulere feni to bale se
Ba oku iseotan a o pada jeran to jerin lo

Suurulere feni to bale se
Ba oku iseotan a o pada jeran to jerin lo

Ara
Surulere

a o pada jeran to jerin lo
surulere

Feni to bale se
Ba oku o


ipo to wu ki o wa
Mama se rora re pin
Eni ti ko ni loni ole pada wa ni Lola
Surulere feni to bale se lo mokan bale
Hoho pada jeran to jerin lo

ara
Surulere

fokan bale o oh pada jeran to jerin lo
surulere

fokan bale ninu Oluwa
surulere


suuru lo ran jobu lowo to fi bori idanwo
Josefu ni Suru lo fi pada wa joba
Oni suuru won ti ni ko ni je ibaje
Loni suuru o oh pada yin olorun logo


toriwipe
surulere


a o jeran to jerin lo
surulere


Oma lo sibi Giga oda ju
Surulere


agon sa ni sara
Lojo yen ninu iwe mimo
Sugbon lojo ogbo re
Olorun pada fun lomo
Mama lo ni suuru
O oh fehin re Gbe omo jo
Gbogbo aye a ba o yo wa ba o yin olorun logo

toriwipe
surulere

gbagbo ninu jesu
surulere



olorun to da oju
Ko le se Alia yi riran
Olorun to da eti
Ko le se alia yi gboran
Aseda to da o oh
Oti mo ohun to fe je
Io fokan bale aye re a dara

toriwipe
surulere

olere
surulere

feni to bale se
surulere

Ba oku ise Otan
surulere

bekun pe dale kan
surulere

Ayo n bo Lowuro so gbo
surulere


suurulere
surulere

igbagbo lafin gbare
surulere

Ba oku ise otan
surulere




Track 6 - Pansa fura

pansa o fura ni pansa fi ja sina

Aja o fura laja fi Jin
Onile ti ko ba fura
Oie ni oko
Onigbagbo efura
Opin aye ti de


pansa o fura
Ni pansa fi ja sina
Aja o fura
Laja fi jin
Onile ti ko ba fura
Ole ni o ko
Oni gbagbo efura
Opin aye ti de

pansa o fura
pansa o fura ni pansa fi ja sina aja o fura laja fi jin onile ti o ba fura ole ni o ko oni gbagbo efura opin aye ti de


Ogbon kigbe lode o fohun ni gboro oke tantan fun gbogbo kristaini ema segbo oh eyin omo olorun oni gbagbo efura opin aye ti de. Oni gbagbo di amure oju Ogun le ohun aye yi maje ko da o pada ronti aya loti to foju weyin lojo yen oni gbagbo efura opin aye ti de.


pansa o fura
pansa o fura ni pansa fi ja sina aja o fura laja fi jin onile ti o ba fura ole ni o ko oni gbagbo efura opin aye ti de.


ore ti oni yen o le da o pada egbon ti o ni yen ole da o pada duro de jesu oludande re oni gbagbo efura opin aye ti de.oro tolorun wa so otiiin sele oni lopin aye oh igba ewu ma de orile ede wa ma dide sira won otiin sele yeh oh ejeka sora


pansa o fura
pansa o fura ni pansa fi ja sina aja o fura laja fi jin onile ti o ba fura ole ni o ko oni gbagbo efura opin aye ti de


ejeka fura
pansa o fura

ejeka fura
ni pansa fi ja sina aja o fura laja fi jin onile ti o ba fura

onile ti o fura
ole ni o ko

ole ko won lo ni ooooh
oni gbagbo efura opin aye ti de

oni gbagbo efura opin aye ti de oooh o ti de
oni gbagbo efura opin aye ti de


oni gbagbo efura opin aye ti de oooooooh
oni gbagbo efura opin aye ti de

oro ti bibeli so malon tiun sele aye egbo oh
oni gbagbo efura opin aye ti de

afomo sowo apaniyan won po ni gboro oh kolorun so wa ooooh
oni gbagbo efura opin aye ti de

opolopo lon wuwa Ibaje ton fii sayo abeori
oni gbagbo efura opin aye ti de

opolopo Ohun egbin lori pepe olorun ao ti seyi si
oni gbagbo efura opin aye ti de

opin aye ti de oni gbagbo eyiwapada ko to pe
oni gbagbo efura opin aye ti de

kristaini ti o ba fura on be ninu ewu iparun oooooooooh
oni gbagbo efura opin aye ti de

oni gbagbo efura opin aye ti de ooooooooh
oni gbagbo efura opin aye ti de
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.

Comments for Surulere lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol at the bottom of the calculator
2| symbol to the left of the camera
3| symbol at the top of the target
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid