song lyrics / Pelumi Deborah / E Ti Tobi to Jesu lyrics  | FRen Français

E Ti Tobi to Jesu lyrics

Performers Pelumi DeborahSoundmindproEmmanuel Edunjobi

E Ti Tobi to Jesu song lyrics by Pelumi Deborah official

E Ti Tobi to Jesu is a song in Yoruba

Oluwa tobi ni Sioni, O si j'oba lori gbogbo orile-ede
(The Lord is great in Zion, he reigns over all the nations)
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si l’eru.
(Let them praise his great and awesome name.)
Gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
(The earth trembles at your name, they sing)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Awon orun na n s’eleri, won n f’oribale niwaju ite re, won so wi pe
(The Heavens testify, they bow their heads before your throne, saying)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Won ni e ti tobi to ooo Oluwa wa
(They say you are great oh our Lord)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Won ni e ti tobi to ooo Oluwa wa o
(They say you are great, oh our lord)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Awon oke nla nla wo n foribale o tori iwo ni Ogo ati Ola ju oke nla ikogun wonni lo o
(The great mountains bow down because you are more in glorious and majestic than the everlasting mountains)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Iwo ti Olorun ji dide kuro ninu oku, lati gba wa kuro ninu ibinu ti mbo o
(You who God resurrected from the dead to save us from the coming wrath)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Iwo Oluwa Olorun to n gbe laarin awon Kerubu, to po ni ipa ati agbara o eh eh
(You who dwell in the midst of the Cherubims, abundant in power and strength )
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
A ni gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
(The earth trembles at your name, they sing)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Awon orun na n s’eleri, won n f’oribale niwaju ite re, won so wi pe
(The Heavens testify, they bow their heads before your throne, saying)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Won ni e ti tobi to ooo Oluwa wa
(They say you are great oh our Lord)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Ipekun ola, ipekun iye eh eh e ti tobi to ooo
(The epitome of honour and life, you are great)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Ireti wa o, Eri wa o e ti tobi to ooo
(Our hope, our testimony, you are great)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Itansan orun to mole roro roro roro e ti tobi to, aye at'orun mbo o o
(The sunlight that shines so bright, you are great, the earth and the Heavens adore you)
E ti tobi to o [won Juba f'oba Ajunilo], Jesu [Won f’oribale f'oba ajunilo]
(Great are you [they pay homage to the greatest], Jesus [they bow to the greatest])
Jordani ri o o pada s’eyin, okun ri o o sa, e ti tobi to olodumare
(Jordan saw you and turned back, the sea saw you and fled, you are great, the Almighty)
Eti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)

Ab’etiluk’ara bi ajere, baba mi agba oye, e ti tobi to
(He who has ears all over, the highest in ranks you are great)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Tori na, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
(Therefore, the whole world trembles at your name, they sing)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Awon orun n s’eleri, won n f’ori ba’le niwaju ite re
(The heavens testify, they bow down before your throne)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Won ni e ti tobi to o, Oluwa wa
(They say you are great, Our Lord)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Gbongbo idile Jese Jesu okan mi f’ori ba’le o, o so wipe
(The root of Jesse, my heart bows and says)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Ipekun ola, Ipekun oro, Ipekun agbara o eti tobi to oo
(The encapsulation of honour, riches and power you are great)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Ola ati ola nla ni owa ni iwaju re, Ipa ati ewa mbe ninu ibi mimo re o
(Honour and Majesty sorround your presence, might and beauty reside in your holy place)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Akaikatan o, Abuubutan o, atobiloye egbe leyin eni andaloro oo eti eti eti tobi to o
(Uncountable, inexhaustible, Strength of the weak, you are great)

E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Jesu, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
(Jesus, the whole world trembles in your name, they sing)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Awon orun na n s’eleri, won n f’oribale niwaju ite re o eh
(Even the Heavens testify, they bow before your throne)
E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)

Won Juba f'ajunilo o
(They pay homage to the greatest)
E ba njuba f'ajunilo eh
(Join me and pay homage to the greatest)
E ba n se’ba f'ajunilo
(Join me and pay homage to the greatest)
E ba n gb'osuba f'ajunilo
(Join me and pay homage to the greatest)
(E ba mi Juba f'ajunilo) Ajunilo Jesu

(E ba n gb'osuba f'ajunilo) Ajunilo
(E ba mi Juba f'ajunilo) gbogbo aye n se'ba
(E ba mi Juba f'ajunilo) awon orun wo n foribale


Gbogbo aye n wariri ni oruko re, won n korin
(The whole world trembles in your name, they sing)

E ti tobi to o, Jesu
(Great are you, Jesus)
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.

Comments for E Ti Tobi to Jesu lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol at the top of the bulb
2| symbol at the top of the envelope
3| symbol to the left of the cross
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid