song lyrics / Funke Ilori / E Kii Seniyan lyrics  | FRen Français

E Kii Seniyan lyrics

Performer Funke Ilori

E Kii Seniyan song lyrics by Funke Ilori official

E Kii Seniyan is a song in English

E kii s'eniyan o to le pa'ro
E kii s'eniyan o to le tan mi je
Awimayehun oba ti kii s'eniyan
E kii s'eniyan Olorun leje
E kii s'eniyan o to le pa'ro
E kii s'eniyan o to le tan mi je
Awimayehun oba ti kii s'eniyan
E kii s'eniyan Olorun leje

Olorun kii s'eniyan ko le seke
E kii s'eniyan o
Oluwa emi gbogbo eniyan leje
E kii s'eniyan o
Ayidayida ko si ninu re
E kii s'eniyan o
Imo Re duro titi aye
E kii s'eniyan o
Iro inu Re lati irandiran ni
E kii s'eniyan o
Ologbon ninu alagbara ni ipa
Ta'lo le sagidi Si
Ohun gbogbo lati odo Re lo ti wa
E kii s'eniyan Olorun leje

E kii s'eniyan o to le pa'ro
E kii s'eniyan o to le tan mi je
Awimayehun oba ti kii s'eniyan
E kii s'eniyan Olorun leje

Titobi ni igbimo alagbara ni ise
E kii s'eniyan o
O mohun gbogbo O le sohun gbogbo
E kii s'eniyan o
Kii ba idajo ati otito je
Onidajo olododo
O nwa gbogbo aya O m'ete ironu
E kii s'eniyan o
Iranlowo alainibaba Oko awon opo
Olutoju eniyan
Awosanmo ni ibora fun O
E kii s'eniyan o
Orun ati awon orun ko le gba O
E kii s'eniyan o Olorun leje

E kii s'eniyan o to le pa'ro
E kii s'eniyan o to le tan mi je
Awimayehun oba ti kii s'eniyan
E kii s'eniyan Olorun leje

Lati 'randiran ni odun Re
Igba atijo O fi ipile aye sole
Orun awon orun si ni ise Re
Won o segbe sugbon Iwo kii ti
Nitoto won o gbo bi aso
Bi ewu ni Iwo yoo paaro won
Ijoba Re wa titi aye
E kii s'eniyan o

Oro Re kii ye o
Oro Re kii ye o
Okan na lana, loni, lola
Oro Re kii ye o
Alewilese dependable God
Oro Re kii ye o
Olorun eri, Olorun majemuni
Oro Re kii ye o
O le pe die sugbon Y'oo mu se
Oro Re kii ye o
Alewilese dependable God
Oro Re kii ye o
Lyrics copyright : legal lyrics licensed by Lyricfind.
No unauthorized reproduction of lyric.
Writer: Funke Ilori
Copyright: O/B/O DistroKid

Comments for E Kii Seniyan lyrics

Name/Nickname
Comment
Copyright © 2004-2024 NET VADOR - All rights reserved. www.paroles-musique.com/eng/
Member login

Log in or create an account...

Forgot your password ?
OR
REGISTER
Select in the following order :
1| symbol to the left of the padlock
2| symbol to the left of the house
3| symbol at the bottom of the clock
grid grid grid
grid grid grid
grid grid grid